terça-feira, 10 de maio de 2022

Campainha

                     Aago ẹnu ọ̀nà (campainha)





Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).

Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Tẹ aago ẹnu ọ̀nà, s. Tocar a campainha.

Tẹ̀, v. Seguir. Apertar, espremer, pressionar. Curvar, abaixar, inclinar-se. Pisar com os pés, calcar, andar. Abraçar, dobrar.
Tẹ̀, adj. Tarado, pervertido.
Tẹ́, v. Cair em desgraça, ser chato, ser sem graça, ser aborrecido. Ser sem gosto, ser insípido. Colocar, estender esteira, estender toalha etc.

segunda-feira, 9 de maio de 2022

- Afropaty

Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé.

Uma preta rica que costuma usar roupas de grife (afropatypreta patrícia).


https://mobile.facebook.com/story.php?story_fbid=394971869037873&id=102677458267317&_rdc=1&_rdr

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://marciatravessoni.com.br/entretenimento/o-que-significa-ser-uma-afropaty-ou-preta-patricia/

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).

Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Obìnrin ọlọ́rọ̀, s. Mulher rica.

Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, s. Uma preta rica.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó sábà máa ń wọ aṣọ ìgbàlódé, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa de grife.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ olówó-ńlá tàbí ohun-ọ̀ṣọ́ dídán yanranyanran, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupas caras ou joias brilhantes.

Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ tó dáa gan-an, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa magnífica.

Ọmọbìnrin bàbá olówó kan tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé, s. Patricinha. A filha de um pai rico que costuma usar roupas de grife.

Ọ̀dọ́bìnrin ọlọ́rọ̀ kan tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Patricinha. Uma jovem rica cujos pais compram roupas de grife para ela.

Ọ̀dọ́bìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Petricinha. Uma patricinha preta cujos pais compram roupas de grife para ela.


- Mercadorias (àwọn ọjà)

Àwọn ohun ọ̀ṣọ́ ilé, ohun-èlò, ẹ̀rọ tí a ń lò nínú ilé àti ohun abánáṣiṣẹ́.

Móveis, utensílios, eletrodomésticos e equipamentos eletrônicos.

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Tábìlì, s. Mesa.

Àga, s. Cadeira.

Àpótí ìjókòó, s. Banco.

Àpótí ẹrù, s. Baú. 

Kọ́bọ́ọ̀dù, kọ́bọ́dù, s. Armário.

Kámẹ́rà, s. Câmera. 

Àwọn kámẹ́rà àti gọgọwú tẹlifíṣọ̀n aríléróde abẹ́lé, s. Câmeras e monitores de circuitos fechados de TV.

Tẹlifíṣọ̀n, s. Televisão.

Rédíò, s. Rádio.

Fóònù alágbèéká, s. Celular, telefone celular.

Kọ̀ǹpútà alágbèéká, s. Notebook.

Kọ̀mpútà, s. Computador.

Fóònù tó lágbára, fóònù ìgbàlódé, s.  Smartphone.

Tẹlifóònù, s. Telefone.

Ohun tí wọ́n fi ń gbọ́ orín bọ etí, ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń gbọ́ orin sétí, s. Fone de ouvido, um dispositivo para ouvir música.

Àwọn ìhùmọ̀ ìgbọ́ròó láti túbọ̀ mú kí ìwọ̀n agbára ìgbọ́rò, s. Aparelhos auditivos para maximizar a audição, aparelhos auditivos para ampliar qualquer audição residual. 

Ẹ̀rọ ńlá tí mo fi ń gbọ́ràn sí, s. Enorme aparelho de audição.

Ìhùmọ̀ ìgbọ́ròó, s. Aparelho auditivo.

Àwọn ohun agbọ́rọ̀jáde ti a ń gbékọ́ etí fún àwọn tí ó lekoko fún láti gbọ́rọ̀, s. Fones de ouvido para os que têm dificuldade de ouvir.

Rédíò alágbèéká kan tí ó ní ẹ̀rọ amúnáwá, aláfọwọ́yí, tí a ṣe mọ́ ọn, s. Um rádio portátil com um gerador manual embutido.

Rédíò kékeré kan tó ní bátìrì tuntun, s. Um pequeno rádio com uma bateria nova.

Rédíò alágbèéká, s. Rádio portátil.

Ẹ̀rọ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, ẹ̀rọ gbohùngbohùn, s. Caixa de som, alto-falante.

Búrọ́ọ̀ṣì, s. Escova.

Búrọ́ọ̀ṣì kan ti a fi ń gbẹ irun, s. Escova secadora.

Ẹ̀rọ ìgbẹrun, s. Secador de cabelos.

Ẹ̀rọ ti a fi ń gbẹ aṣọ, s. Secador.

Ẹ̀rọ tó mú irun orí tọ́, s. Alisador de cabelo, chapa alisadora. 

Ẹ̀rọ ìlọǹkan, s. Liquidificador.

Ìfúntí, s. Espremedor de frutas para o fabrico de vinho.

Ẹ̀rọ tó lè yọ omi èso jáde, s. Extrator de suco de frutas.

Àwọn ẹ̀rọ ìpoǹkanpọ̀ oníná, s. Batedeiras.

Àwọn ẹ̀rọ ìgbọ́únjẹ, s. Processadores de alimentos. 
Àwọn ohun èlò tá a fi ń se oúnjẹ, s. Utensílios de cozinha.
Ohun èlò tó ń lo iná mànàmáná, s. Panela elétrica.
Ìkòkò, s. Pote, vasilha.
Ìkòkò ìse-oúnjẹ, s. Panela. 
Ohun-èèlò tàbí ìṣàgbékalẹ̀ láti yan ẹran tí wọ́n máa jẹ, ohun-èèlò tàbí ìṣàgbékalẹ̀ tá a lò láti yan ẹran, s. Utensílio ou instalação para assar carne para comer, churrasqueira.
Ẹ̀rọ tí a ń lò nínú ilé tá a lò láti dẹ́ran àti àwọn ohun jíjẹ mìíràn, s. Eletrodoméstico usado para fritar carne e outros alimentos, fritadeira. 
Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé oníná, s. Impressora elétrica.
Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé alátẹ̀yípo ńlá, s. Grande impressora rotativa.
Ẹ̀rọ ìfọṣọ, s. Máquina de lavar. 
Ẹ̀rọ kan tó máa ń ya nǹkan sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, s. Centrífuga.
Ẹ̀rọ kan tí yóò fi agbára fún oyin jáde, s. Uma centrífuga que extrai o mel.
Ẹ̀rọ ìṣaǹkan tí ń yí bírí láti yọ àwọn èèpo kúrò àti láti mú kí agbára òróró tajútajú náà pọ̀ sí i, s. Centrífuga para remover a casca e para aumentar a concentração de óleo volátil.
Táǹkì, s. Tanque.
Ààrò tí wọ́n ti ń dáná igi, s. Fogão a lenha.
Àdìrò, ààrò, ẹ̀rọ ìdáná, s. Lareira, forno. 
Ẹ̀rọ amú-nǹkan-gbóná tí wọ́n ń pè ní microvave, s. Forno de micro-ondas.
Àrò, ẹ̀rọ ìdáná, s. Forno, fogão, estufa, fornalha. Sítóòfù (do inglês stove), s. Fogão.
Àdìrò tó ń lo iná mànàmáná, s. Forno elétrico.
Ihò omi kan, ibi kòtò olómi, ẹ̀rọ omi, s. Bebedouro.
Ẹ̀rọ tó máa ń fọ omi mọ́, s. Purificador de água.
Fìríìjì, s. Freezer.
Ẹ̀rọ̀ amú-nǹkan-tutù, ẹ̀rọ amúǹkantutù, ẹ̀rọ tí ń mú ǹkan tutù, ẹ̀rọ amómitutù, fìríìjì, s. Geladeira, refrigerador.
Àga tó fẹ́ràn jù, s. Cadeira favorita, sofá.
Ìjókòó gbọọrọ onítìmùtìmù, s.  Uma cadeira reclinável confortável, sofá.
Àga ìrọ̀gbọ̀kú, àga ìgbafàájì, s. Cadeira. reclinável, sofá.
Àga ìnàyìn, s. Sofá.
Àga onítìmùtìmù, s. Estofado.
Kọ́tìnì, s. Cortina.
Ilé ìtajà ńlá kan, s. Uma grande loja.
Pẹpẹ ìkówèésí, pẹpẹ-ìwé, pẹpẹ ìkẹ́rùsí, pẹpẹ, s. Prateleira.
Pẹpẹ, s. Prateleira, estante, altar.
Àwọn àpótí ìkówèésí, s. Prateleiras de livros.
Pánẹ́ẹ̀lì tó ń lọ fún tẹlifíṣọ̀n, s. Painel para 
TV.
Àwọn pẹpẹ onígíláàsì, s. Balcões de vidro.
Káńtà, s. Balcão.
Ibi ìkówèésí, pẹpẹ ìkówèésí, pẹpẹ-ìwé, s. Estante para livros.
Àwọn àgbékọ́ amáraró, s.  Suportes para os pés.
Orí-ikọ́, oríkọ́, s. Anzol, colchete, gancho. 
Ìgangan, s. Cabide. Um tipo de peixe.
Ibi ìkáṣọsí,  àpótí aṣọ, s. Guarda-roupa, roupeiro. 
Bẹ́ẹ̀dì, ibùsùn, s. Cama.
Bẹ́ẹ̀dì ọmọ ọwọ́, s. Cama de bebê, berço.
Bẹ́ẹ̀dì alágbèékà, s. Beliche.
Bẹ́ẹ̀dì tó bá ọmọdé mu, bẹ́ẹ̀dì fún ọmọdé, s. Cama infantil.
Mátírẹ́ẹ̀sì, s. Colchão.
Mátírẹ́ẹ̀sì tó jẹ́ pé aṣọ tí wọ́n fi ṣe é kì í gbọn ìdọ̀tí tín-íntìn-ìntín, s.  Colchão de fibras sintéticas.
Mátírẹ́ẹ̀sì oníkoríko tí wọ́n fi ẹní bò, s. Colchão de palha, coberto por esteira.
Mátírẹ́ẹ̀sì oníkoríko, s. Colchão de palha.
Àpótí ìkọ̀wé, s. Escrivaninha.
Kọ́bọ́ọ̀dù kan tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀  ibi-ìkó-nǹkan-sí , s. Um armário que tem várias gavetas, cômoda. 
Àpótí ìkó-ǹkan-sí tuntun sí ilé ìdáná, àpótí ìkó-ǹkan-sí tuntun sí kíṣìnnì, s. Novo armário de cozinha.
Tábìlì onígi, s. Mesa de madeira. 
Tábìlì onígíláàsì, s. Mesa de vidro. 
Tábìlì tí wọ́n fi òkúta mábù ṣe, s. Mesa de mármore.
Tábìlì tí a fi akọ òkúta ṣe, s. Mesa de granito.
Tábìlì tí a fi rúbì ṣe, s. Mesa de rubi.
Káńtà tá à ń lò nínú kíṣìnnì, s. Balcão usado na cozinha, balcão de cozinha.
Àkójọ ọ̀bẹ, àpapọ̀ àwọn ọ̀bẹ, s. Jogo de facas. 
Àkọ̀ tàbí àpótí tá a lò láti fi àwọn fọ́elétricaọ̀kì, ṣíbí àti ọ̀bẹ sínú rẹ̀, s. Um estojo ou caixa usado para guardar garfos, colheres e facas dentro dele, faqueiro.
Àgé, s. Vasilha para apanhar água, chaleira.
Àgé tó ń lo iná mànàmáná, s. Chaleira elétrica.

Ohun èlò ìsekọfí, ohun tí a fi ń ṣe kọfí, s. Cafeteira.

Ife ìmukọfí, s. Xícara de café.

Ohun-èlò tàbí ẹ̀rọ nínú èyìtí a gbé àwọn ọmọ àgbàdo láti ṣe gúgúrú, s. Vasilha ou máquina em que se colocam grãos de milho para fazer pipocas, pipoqueira. 

Ààrò oníná tá a lè yan búrẹ́dì, ààrò oníná tí a fi ń yan búrẹ́dì sílẹ̀, s. Torradeira de pão. 

Àwọn àwo oúnjẹ tí wọ́n fi fàdákà àti àwọn mẹ́táàlì ṣíṣeyebíye mìíràn ṣe, s. Aparelhos de jantar de prata e de outros metais preciosos.

Àwọn abọ́ ìmumi, s. Cálices.

Àwọn àwo, s. Pratos. 

Àwọn ife, s. Copos.

Ẹ̀rọ kan tó lè fi omi díẹ̀ sí i sí àyíká rẹ nínú ìyàrá kan, s. Um dispositivo que pode umedecer seu ambiente dentro de uma sala, umidificador.

Òṣùwọ̀n tí ń díwọ̀n ariwo ní ìwọ̀n decibel, s. Medidor de som em decibéis.

Òṣùwọ̀n onídíjítà kan tó máa ń wọn ìwọ̀n ìfúnpá, òṣùwọ̀n onídíjítà kan tó máa ń wọn ẹ̀jẹ̀ ríru, s. Um monitor digital que mede a pressão arterial, um medidor de pressão digital, um monitor digital de pressão.

Àwọn oògùn tó máa ń fà símú, s. Inaladores. 

Òṣùwọ̀n onídíjítà, s. Balança digital. 

Òṣùwọ̀n tó péye, s.  Balança exata.

Ẹ̀rọ tó lo oruku omi láti lọ aṣọ, ẹ̀rọ tó lò  kùrukùru omi láti lọ aṣọ, s. Ferro a vapor.

Ẹ̀rọ ìlọṣọ, ẹ̀rọ tí a fi ń lọ aṣọ, s. Ferro de passar roupa.

Ẹ̀rọ abánáṣiṣẹ́ kan tó lo oruku omi láti lọ aṣọ, ẹ̀rọ abánáṣiṣẹ́ kan tó lò kùrukùru omi láti lọ aṣọ, s. Passadeira a vapor. Uma máquina elétrica que usa vapor para passar roupas.

Èlò táa fi ń dáhò sí nǹkan, ẹ̀rọ ìdá-nǹkan-lu, s. Furadeira.

Ẹ̀rọ kan tí ó lè gún, s. Uma máquina que pode perfurar, furadeira.

Àwọn ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń wa epo jáde látinú ilẹ̀ lónìí, s. Aparelhagem de perfuração moderna.

Ẹ̀rọ tí ó rì, s, Perfuratriz.

Àwọn ayùn ayára bí àṣá tó ń lo iná mànàmáná, s. Serras elétricas de alta velocidade.

Ayùn tó ń lo iná mànàmáná, s. Serra elétrica.

Ayùn ìrẹ́gi, s. Motosserra. 

Ayùn ìrẹ́gi tó ń lo epo mọ́tò, s. Motosserra movida a gasolina.

Ẹ̀rọ ìfabọ́, s. Lavadora de louça automática.

Ẹ̀rọ ìfọbọ́, ẹ̀rọ tó fọ abọ́s. Lavadora de louça.

Ẹ̀rọ tó lè fọ, s. Máquina de lavar. 

Ẹ̀rọ ńlá láti kó àwọn àwókù náà, s. Máquina pesada para limpar os escombros. 

Ẹ̀rọ tí wọ́n fi ń gbálẹ̀, ẹ̀rọ gbálẹ̀ ilé , s. Aspirador de pó.

Maṣíìnì ìránṣọ, maṣín-ìnnì ìránṣọ, ẹ̀rọ ìránṣọ, s.  Máquina de costura.

Fáàànù, ẹ̀rọ àfimí, abẹ̀bẹ̀, s. Ventilador.

Ẹ̀rọ amúlétutù, s. Ar-condicionado.

Ẹ̀rọ ìkọrin àti gbohùngbohùn, s. Amplificador e alto-falante

Ẹ̀rọ gbohùngbohùn, s. Alto-falante.

Makirofóònù, s. Microfone.

Rédíò ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́, s. Autorrádio.

Eré ìdárayá orí kọ̀ǹpútà, s.  Jogos de computador.

Ẹ̀rọ kékeré tá a fi ń wo fídíò, s. Aparelho de DVD portátil.

Fídíò lórí àwo DVD, s. Vídeo em DVD.

Àwo fídíò alodíjítà, s. Disco de vídeo digital, DVD.

Ẹ̀rọ DVD, s. Aparelho de DVD. 

Ẹ̀rọ rẹ́kọ́ọ̀dù, ẹ̀rọ orin aláwo, s. Vitrola.

Giramọfóònù, s. Fonógrafo.

Ẹ̀rọ gbohùngbohùn, ẹ̀rọ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, s. Caixa acústica, caixa de som.

Ẹ̀rọ tó gẹrun, ẹ̀rọ tó gẹ irun, s. Máquina de cortar cabelo, cortador de cabelos.

Àwọn ìfárùngbọ̀n tí ń lo iná mànàmáná, s. Barbeadores elétricos.

Ẹ̀rọ tó gé irun imú, s. Aparador de bigode.

Àtẹ bọ́tìnnì onífunra sí ìfọwọ́kàn, s. Teclado de toque.

Àtẹ bọ́tìnnì, s. Teclado. 

Àwọn òòlù àpótíi bọ́tìnnì, s.  Martelos de teclado, martelos de caixa de botão.

Gìtá, s. Violão, guitarra. 

Gòjé, s. Violino, alaúde, viola. 

Móló, bóló, s. Violão hauçá. 

Ohun èlò ìkọrin olókùn tín-ín-rín, s. Instrumento de cordas.

Lírè, s. Lira.

Háàpù, s. Harpa.

Mandolin, s. Bandolim. 

Gòjé-olóhùn, s. Violoncello, cello.

Ọwọ́ ìlẹ̀kùn, s. Maçaneta.

Rìmóòtù, s. Controle remoto.

Ẹ̀rọ ìsanwó, s. Máquina de pagamento.

Ẹ̀rọ ìsanwó-gbowó adáṣiṣẹ́, ẹ̀rọ tó ń gbowó tó sì ń sanwó ní báńkì (ATMs), s. Máquina de pagamento automatizada, caixa eletrônico.

Ohun èlò alágbèéká tó ń ṣiṣẹ́ bíi kọ̀ǹpútà, ẹ̀rọ tablet, s. Tablet, dispositivo portátil que funciona como computador.

Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́, s. Carro de som.

Kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́ta, s. Triciclo.

Kẹ̀kẹ́ ọmọdé, s. Carrinho.

Kẹ̀kẹ́ tí wọ́n fi ń ti àwọn ọmọ ọwọ́ kiri, kẹ̀kẹ́ téèyàn fi ń ti ọmọ ọwọ́ káàkiri, kẹ̀kẹ́ ọmọdé, s. Carrinho de bebê.

Kẹ̀kẹ́ onígi tí wọ́n fi ń ti ẹrù, s. Chukudu. Uma espécie de patinete artesanal de madeira para transportar cargas.

Akoto tí mo máa ń dé lórí alùpùpù, s. Capacete de moto.

Mọtosááikù, alùpùpù, s. Motocicleta, moto. 

Ọkọ̀ orí yìnyín, s. Moto de neve.

Alùpùpù tí ọmọdé ń lò, s. Moto infantil.

Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí ọmọdé ń lò, s. Carro que criança usa.

Básíkùlù, kẹ̀kẹ́, s. Bicicleta.

Ẹ̀rọ àmúdán, s. Enceradeira.

Agbada onírin, s. Frigideira de ferro. A frigideira é uma panela usada pra fritar carnes, batatas, ovos, legumes e outros alimentos.  Agbada, s. Vasilha utilizada para cozinhar ou fritar àkàrà. 

Páànù tí wọ́n fi ń dín nǹkan kaná, s. Frigideira. Páànù, s. Panela, caçarola, prato esmaltado.

Ìhùmọ̀ agbésọfúnni láti ojúde òfuurufú tí ó rí bí ọ̀pá àti ìhùmọ̀ aṣàwárí mẹ́táàlì, s. Sonda parecida com bastão e detector de metais, sonda que se parece com uma haste e um detector de metais.







quarta-feira, 27 de abril de 2022

- Constituição do Estado da Diáspora Africana.

 Ìwé òfin Orílẹ̀-èdè tó máa ń kó àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tó wà lájò pọ̀.

Constituição do Estado da Diáspora Africana.

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://thestateofafricandiaspora.com/wp-content/uploads/2022/01/Constitution.pdf

https://thestateofafricandiaspora.com/#

https://thestateofafricandiaspora.com/descubra-o-novo-governo-do-estado-da-diaspora-africana/


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Àkọsílẹ̀ Òfin Orílẹ-Èdè, ìwé òfin orílẹ̀-èdè, s. Constituição nacional. 

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Orílẹ̀-èdè, s. Nação, país.
Orílẹ̀, s. Grupo de origem ou clã.
Èdè, s. Língua, idioma, dialeto, linguagem.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
Máa, part. v. Usada como outra opção para marcar o tempo futuro do verbo, admitindo o pronome pessoal de uma sílaba.
Máa, v. aux. Indica uma ação habitual, costumeira.
Máa ń, a máa, adv. pré v. Ter costume de, estar acostumado, ter maneira de (fazer algo). Emprega-se o presente do indicativo para expressar uma ação constante ou habitual.
Máa, maa, obs. : Colocado antes do verbo, dá um sentido polido a uma ordem.

, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.

, adj. Suficiente, bastante.
, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome  e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão.
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.

, v. Alinhar, ficar na fila, colocar em ordem, arrumar.

Tòò, adv. Sonoramente, ruidosamente.

Ti lọ, adj. Desaparecido.

, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.

, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.

Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

Kópọ̀, v. Reunir, recolher, colecionar. 

Àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tí wọ́n wà lájò, Àwọn adúláwọ̀ ará Áfíríkà tí wọ́n wà lájò, s. Africanos da diáspora.

Àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tí a tú káàkiri, s. Africanos dispersos, africanos da diáspora. 

Àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà, àwọn aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà, àwọn adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà, s.  Afro-americanos.

Àwọn ọmọ Áfríkà Kàríbẹ́ánì, àwọn aláwọ̀dúdú ará Kàríbẹ́ánì, àwọn adúláwọ̀ ará Kàríbẹ́ánì, s.  Afro-caribenhos.

Àwọn ọmọ Áfríkà Kánádà, àwọn aláwọ̀dúdú ará Kánádà, àwọn adúláwọ̀ ará  Kánádà, s. Afro-canadenses.

Àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà Látìnì, àwọn aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà Látìnì, àwọn adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà Látìnì, àwọn ọmọ Áfríkà tí wọ́n ń gbé ní Amẹ́ríkà Látìnì, àwọn aláwọ̀dúdú tó ń gbé ní Amẹ́ríkà Látìnì, àwọn adúláwọ̀ tí ń gbé ní Amẹ́ríkà Látìnì, s. Afro-latino-americanos.

Àwọn ọmọ Áfríkà Ásíà, s. Afro-asiáticos.

Àwọn ọmọ Áfríkà Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn ayé, àwọn ọmọ Áfríkà tó ń gbé ní Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn ayé, àwọn adúláwọ̀ ará Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn ayé, àwọn adúláwọ̀ tí ń gbé ní Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn ayé, s. Africanos ou negros que vivem no Oriente Médio, zanje.

Àwọn ọmọ Áfríkà tí wọ́n ń gbé ní  kọ́ńtínẹ́ǹtì kékeré ti Íńdíà, s. Africanos que vivem no subcontinente indiano, sidis.

Tó máa ń kó àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà tó wà lájò pọ̀, adj. Que reúne expatriados africanos.

Ọ̀mọ̀, s.Uma árvore cuja madeira é utilizada para fazer o tambor bẹ̀mbẹ́. Cordia millenii (Boraginaceae).
Ọmọ, s. Filho, criança, descendência.
Ọmọbìnrin, s. Filha.
Ọmọkùnrin, s. Filho. 
Ọmọ àgbàbọ́, s. Filho adotivo.
Ọmọ àgbo, ọmọ ọwọ́, ọmọ ọmú, s. Bebê, criança.
Ọmọ aládé, s. Príncipe, princesa.
Ọmọ aláìloobiọmọ òkú, s. Órfão.
Ọmọ àlè, s. Bastardo, o filho da outra.
Ọmọbíbí, s. Nascimento de uma criança.
Ọmọdé, s. Criança.
Ọmọ̀dọ̀, s. Criada, serviçal.
Ọmọdọ́mọ, s. De criança em criança, de tempos em tempos.
Ọmọ ènìà, s. Ser humano, cavalheiro.
Ọmọ ẹ̀hìn, s. Discípulo, seguidor, aprendiz.
Ọmọge, s. Mulher jovem, criada.
Ọmọge ìbílẹ̀, ọmọ ìlú, s. Nativo da terra.
Ọmọ iléwé, akẹ́kọ̀ọ́, akẹ́kọ́, ọmọ ilé-ẹ̀kọ́, ọmọ-sùkúrù, s. Aluno, estudante.
Ọmọ ìlú, s. Nativo da mesma cidade, nativo da mesma região.
Ọmọ jẹ́jẹ́, s. Criança fina, gentil.
Ọmọkọ́mọ, s. Qualquer criança, uma criança má.
Ọmọ làlà, s. O primeiro neto.
Ọmọlé, s. Grupo familiar.
Ọmọlẹ́hìn, s. Seguidor.
Ọmọlójú, s. Neto, menina dos olhos.
Ọmọlúwàbí, s. Pessoa de caráter, cavalheiro e educado.
Ọmọ ọba, s. Filho do rei, príncipe, princesa.
Ọmọnìkéjì, s. Companheiro, vizinho.
Ọmọ ọmọ, s. Neto.
Ọmọ-ọmú, s. Criança em fase de amamentação.
Ọmọpẹ́, s. Denominação de uma criança que passa dos nove meses de gestação.
Ọmọṣẹ́, s. Aprendiz de trabalho.
Ọmọ tuntun, s. Recém-nascido, bebê.
Ọmọ wáhàrí, s. Filho de uma escrava tomada como esposa.
Ọ̀mọ̀wé, s. Pessoa educada, sábia.
Ọ̀mọwẹ̀, s. Nadador.

Ẹlẹ́yàpúpọ̀, s. Indivíduo mestiço, colorido ou multirracial.
Adúláwọ̀, s. Negro.

Ènìyàn dúdú, s. Negro.
Dúdú, v. Ser preto.
Dúdú, adj. Negro.

Áfríkà, Áfíríkà, s. África. 

Tí a tú káàkiri, tó wà lájò, adj. Espalhado, disperso.

Tí a bí ní Ẹkùn kẹfà ti Áfríkà, adj. Nascido na Sexta Região de África.

Olórí ìjọba, Mínísítà Àgbà, s. Primeiro-ministro.

Igbákejì Mínísítà Àgbà, s. Vice-primeiro-ministro, primeiro-ministro adjunto.


quarta-feira, 20 de abril de 2022

Resistência e aculturação entre os povos africanos.

 Ìfaradà  àti  ìyáṣàpadà láàárín àwọn èèyàn Áfíríkà.

Resistência  e aculturação entre os povos africanos.


1. Ìfaradà  àti  ìgbéraga nítorí àṣà ìbílẹ̀ (resistência e orgulho cultural) 

Àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà pẹ̀lú àwọn èdè ìbílẹ̀ tí a fàṣẹ sí

Lista de países africanos com línguas indígenas oficiais.

1. África do Sul: Zulu (22.7%), Xhosa (16%), Sepedi (9.1%), Tswana (8%), Southern Sotho (7.6%), Tsonga (4.5%), Swazi or SiSwati (2.5%), Venda (2.4%), Ndebele (2.1%).

2. Tanzânia: suaíli.

3. Argélia: árabe, berbere.

4. Botsuanatsuana.

5. Burundikirundi.

6. Chadeárabe.

7. Djiboutiárabe.

8. Egitoárabe.

9. Eritreanenhum, de facto: árabe, tigrinia.

10. Etiópiaamárico.

11. Gâmbia: árabe. 

12. Quêniasuaíli.

13. Comoresárabe, comoriano.

14. Lesotosesoto.

15. Líbiaárabe.

16. Madagáscarmalgaxe.

17. Malawichewa.

18. Marrocosárabe, berbere.

19. Mauritâniaárabe.

20. República Centro-Africanasango.

21. Ruandaruanda.

22. Seichelescrioulo de Sycheilles.

23. Somáliasomali, árabe.

24. Suazilândia (Essuatíni)suázi.

25. Sudãoárabe.

26. Tunésiaárabe.

27. Ugandasuaíli.

28. Zimbábue: xona (shona), cheua (nianja), bárue, coissã (koisan), ndau, ndebele, shangani, soto (sotho), tonga, tsuana, venda, xhosa, tshwa, sesoto, kalanga, nambya.

2. Ìyáṣàpadà àti ìgbàmọ́ra (aculturação e assimilação).

2.1 - Àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà pẹ̀lú àwọn èdè ilẹ̀ Yúróòpù tí a fàṣẹ sí- Lista de países africanos com línguas europeias oficiais: Angola, Benin, Burkina Faso, República Democrática do Congo, Congo, Libéria, Mali, Maurício, Moçambique, Namíbia, Níger, Nigéria, Cabo Verde, Senegal, Serra Leoa, Sudão do Sul, Togo, Costa do Marfim, São Tomé e Príncipe, Zâmbia.

2.3 - Àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà tí wọ́n gba ìsìn àwọn olùtẹ̀dó ará Yúróòpù  sínú - Lista de países africanos que adotaram a religião dos colonizadores europeus. Os dez países africanos que apresentaram maior crescimento do cristianismo foram: Angola, Tanzânia, Malawi, Zâmbia, Uganda, Ruanda, Madagascar, Libéria, Quênia e República Democrática do Congo.




Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Àkójọ, s. Coleção, lista, acumulação, poupança.

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. 
Orílẹ̀-èdè Olómìnira, 
rìpóbílììkì, s. Republica.

Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.

Ìpínlẹ̀, s. Fronteira, demarcação, limite entre duas cidades, Estado ( SP, RJ).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Ìlú, s. Cidade, terra, , região, país.
Ìlù, s. Tambor, um tipo de toque de atabaque.
Ìlù, s. Atabaque, tambor.
Ìlu, s. Verruma, perfurante.
Ìlú etí, s. Tímpano.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.

Àwọn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà, s. Países africanos.

Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.
, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.

Ti, àti, conj. E.
Òun, on, conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas.

Pẹ̀lú, Conj. E.

Pẹ̀lú, prep. Com, junto com.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.

, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.

, adj. Suficiente, bastante.
, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome  e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão.
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.

Ti lọ, adj. Desaparecido.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.

Èdè ìbílẹ̀, s. Língua indígena. 

Èdè ìbílẹ̀ tí a fàṣẹ sí, s. Língua indígena oficial.

Àwọn èdè ilẹ̀ Yúróòpù, s. Línguas europeias.

Àṣà ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn aláwọ̀ funfun, s. Cultura branca.  

Àṣà ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn olùtẹ̀dó ará Yúróòpù, s. A cultura dos colonizadores  europeus.

Nínú, prep. Dentro, no interior de.
Inú, s. Estômago, ventre, interior, interno, no íntimo de.
Láàárín, láàrin, prep. No meio de, entre.

Lára, prep. Entre, no meio de, em.
Lára, adj. Corporal, material. 
Lára, adj. Forte, corpulento, gordo.
Lara, v. Ter ciúmes, ter inveja de.
Lárà, s. Tipo de arbusto que produz óleo de rícino. Ricinus communis (Euphorbiaceae).
Láre, v. Ter direito, ter justiça.
Ẹ̀dà èèyàn, s.  Homem, ser humano. O indivíduo que pertence à espécie humana.
Èèyàn, s. Povo, gente, pessoas.
Ajọ̀bọ, irúọmọnìyàn, àwọn irúọmọnìyàn, s.  Hominoidea. A superfamília de mamíferos, incluindo macacos antropóides e os seres humanos.
Ọmọnìyàn, ọmọ ènìyàn, s.  Homo sapiens. 
Ènìà, ènìyàn, s. Pessoa. É também usado de forma impessoal para significar povo, seres humanos, alguém. 
Ènìyàn àkọ́kọ́, s. Primeiro homem. Èmi Ni Ẹni Àkọ́kọ́, Èmi Ni Ẹni Ìkẹyìn - Eu sou o primeiro e o último.
Aráàlú, s. Povo do lugar, da cidade, da região.
Ará, ènìyàn, s. Povo. 
Ọmọ ìlú, ará ìlú, s.  Cidadão. 
Ará ìlú kannáà, s. Compatriota.
Iye ènìyàn inú ìlú, s. População. 
Ọ̀pọ̀ ènìà aláìníláárí, àwọn "ọmọ ìta", s. Plebe, populacho, povo, ralé, populaça.
Ìṣẹ̀ṣe, àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, òfin àtọwọ́dọ́wọ́, s. Tradição. 
Ìṣẹ̀dálẹ̀, s. Costume primitivo, início. 
Àṣà, s. Costume, hábito, moda.
Àtọwọ́dọ́wọ́, adj. Hereditário, tradicional.
Àṣà ìbílẹ̀, s. Cultura.
Àtọwọ́dọ́wọ́ ìdìlé, s. Tradições familiares. 
Àṣà ìbílẹ̀ Áfíríkà, s. Cultura tradicional africana.
Ìpinnu ara ẹni, s. Autodeterminação.
Òmìnira ìfẹ́ inú, s. Livre-arbítrio.
Òmìnira ìfẹ́-inú láti ṣe àwọn ìpinnu tiwọn, s. Livre-arbítrio para tomar suas próprias decisões.
Òmìnira láti yan ìjọba tó wù wọ́n, s. Liberdade de escolher seu próprio governo.
Áfríkà, Áfíríkà, s. África. 
Ìfaradà, s. Resistência. 
Ìyáṣàpadà, s. Aculturação.





domingo, 17 de abril de 2022

- Corredor ecológico triplo a

 Agbègbè ìdáàbòbò kan tí ó ní ìjẹ́pàtàki kárí ayé  tó bẹ̀rẹ̀ láti àwọn òkè ńlá Andes, ìgbó kìjikìji Amasónì  títí dé  Òkun Àtìláńtíìkì.

Uma área protegida que tem importância internacional que se estende desde os Andes, a selva Amazônica até o Oceano Atlântico. 

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://www1.folha.uol.com.br/ambiente/2019/10/para-criador-do-corredor-triplo-a-na-amazonia-preservacao-se-sobrepoe-a-soberania-brasileira.shtml

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Agbègbè kan láti dáàbò bo àyíká tí ó ní ìjẹ́pàtàki kárí ayé tó bẹ̀rẹ̀ láti   àwọn òkè ńlá Andes, ìgbó kìjikìji Amasónì  títí dé  Òkun Àtìláńtíìkì, s. Uma área para proteger o meio ambiente que tem importância internacional que se estende desde a Cordilheira dos Andes, a Selva Amazônica até o Oceano Atlântico.

Agbègbè ìdáàbòbò kan tí ó ní ìjẹ́pàtàki kárí ayé  tó bẹ̀rẹ̀ láti  àwọn òkè ńlá Andes, ìgbó kìjikìji Amasónì  títí dé  Òkun Àtìláńtíìkì, s. Uma área protegida que tem importância internacional que se estende desde os Andes, a selva amazônica até o Oceano Atlântico. 

Agbègbè, s. Arredores, periferia, subúrbio, cercanias. 

Ìdáàbòbò, s. Proteção.

Àwọn akéde kan, s. Alguns publicadores. 
Kàn án mọ́gi!, v. imper. Crucifica-o!, Para a estaca com ele!  Bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Começou a acusá-lo.
Ìkan, ọ̀kan, num.  Um.
Kan, v. Tornar azedo.
Kan, adj. Amargo, ácido, azedo. Longe, ao largo.
Kan, num. e art. Um, uma.
Kàn, adv. pré. v. Somente, simplesmente.
Kàn, v. Atingir, tocar, alcançar. Pregar com um martelo. Bater na porta, bater com a cabeça como um carneiro. Girar, retornar, fazer um rodízio. Referir-se a, aludir, recorrer. Devolver, interessar alguém.
Kán, v. Pingar, gotejar ( a chuva ou qualquer líquido). Quebrar, partir, estalar algo sólido.
Mọ́gi, s. Estaca. 

, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.
, adj. Suficiente, bastante.

, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome  e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão.
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.
Àwọn ọjọ́ òkùnkùn, s. Dias de escuridão.

Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.

Ti lọ, adj. Desaparecido.

, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.

, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.

Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.

Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná (l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.

Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.

, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Ti, àti, conj. E.
Pẹ̀lú, Conj. E.

Òun, on, Conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas. Òjó on Àjàdí - Ojô e Ajadi.

Tí ó ní ìjẹ́pàtàki kárí ayé, adj. Que tem importância internacional.

Ìjẹ́pàtàki, s. Importância.

Kárí, v. Ir ao redor, em torno de. 

Àyè, s. O fato de estar vivo.

Aláyè, s. O senhor da vida. 

Ẹ̀mí, ìyè, wíwà láàyè, ìgbésí ayé, ayé, yíyè, ààyè, ìwàláàyè, s. Vida.

Àyíká, s. Ambiente.
Ẹ̀kọ́ nípa àyíká, s. Educação ambiental.
Ẹ̀dá, s. Criatura, criação, qualquer criatura viva. Natureza, criação.
Àdánidá, s. Natureza.
Àwọn ìṣòro àyíká, s. Problemas ambientais.
Ìbàyíkájẹ́, s. Poluição.
Ilé Ẹ̀kọ́ Nípa Àyíká, s. Instituto Ambiental.
ILÉ Iṣẹ́ Tó Ń Rí sí Ọ̀ràn Àyíká, s. Ministério do Meio Ambiente.
Ọdún Ìgbógo fún Ibi Rírẹwà Jù Lọ, s. Ano do Paisagismo.
Ìgbèríko, s. Vizinhaça, província, costa. Área rural, zona rural.
Àgbègbè àrọko, s. Zona rural.
Àwọn ìgbèríko, s. Áreas rurais. Nígbà àtijọ́, ìlú Vagnari jẹ́ ìgbèríko èyí tí olú ọba ń ṣàkóso, àwọn lébìrà máa ń yọ́ irin níbẹ̀, wọ́n sì tún ń ṣe àwo ìbolé níbẹ̀ - Nos tempos antigos, Vagnari era uma propriedade imperial rural — uma região controlada pelo imperador — onde os trabalhadores fundiam ferro e produziam telhas de barro.
Tí wọ́n wà láwọn ìgbèríko, adj. Nas zonas rurais.

Ìlétò, abúlé, s. Vila, vilarejo.
Iṣẹ́ àgbẹ̀, s. Agricultura. Kí ló mú káwọn àgbẹ̀ máa ṣí kúrò nílẹ̀ náà? - O que provoca o êxodo rural?
Ìgbésí ayé oko, s. Vida rural.

Ibi-ààbò, ibi-àsálà, s. Refúgio, asilo. Esconderijo.

Ààbò, s. Proteção, refúgio, cobertura, defesa, segurança, escudo.

Dáàbò, v. proteger, defender, abrigar.

Dáàbòbò, v. Proteger.

Láti, prep. Para. Usada antes de verbo no infinitivo. 
Láti dé, prep. Indica de um lugar para o outro. Láti Ẹ̀kọ́ dé Ìbàdàn - De Ekó para Ibadam.
Láti di, prep. Indica de um período para outo. 

Láti, prep. De, desde. É usada depois de um verbo com sílaba dupla e se for seguida de outro verbo. Para verbo de uma sílaba, é opcional.  Èmi kò fẹ́ràn láti jẹ níkàn - Eu não gosto de comer sozinho. Alguma vezes é colocada antes do verbo para expressar propósito. Ó dé lát'àná - Ela chegou desde ontem. Em outros casos, é usada para indicar direção. Ó dé láti ọjà- Ela chegou do mercado.
Bẹ̀rẹ̀, v. Começar, iniciar.
Bẹ̀rẹ̀ sí, v.  Iniciar a, começar a. Tẹ́túlọ́sì bẹ̀rẹ̀ sí fẹ̀sùn kàn án - Tértulo começou a acusá-lo.
Àwọn òkè ńlá Andes, s. Cordilheira dos Andes.
Ìgbó kìjikìji Amasónì, s. Selva Amzônica. 
Òkun Àtìláńtíìkì, s. Oceano Atlântico.